CAC Ìwé Onírúurú 041 | Ko Su Wa Lati Ma Ko Orin Igbani, Ògo F'ọlọrun.



  •  Ko su wa lati ma ko orin igbani 

   Ogo f'Olorun Aleluya! 

   A le fi igbagbo korin na s'oke kikan. 

   Ogo f'Olorun, Aleluya 


Refrain

Omo Olorun ni eto lati bu s'ayo 

Pe ona yi nye wa si, 

Okan wa ns'aferi Re; 

Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo 

Ogo f'Olorun, Aleluya! 


  •  Awa mbe n'nu ibu ife t'o ra wa pada, 

   Ogo f'Olorun Aleluya! 

   Awa y'o fi iye goke lo s'oke orun; 

   Ogo f'Olorun, Aleluya! 


Refrain

Omo Olorun ni eto lati bu s'ayo 

Pe ona yi nye wa si, 

Okan wa ns'aferi Re; 

Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo 

Ogo f'Olorun, Aleluya! 


  •  Awa nlo si afin kan ti a fi wura ko, 

   Ogo f'Olorun Aleluya! 

   Nibiti ao ri Oba Ogo n'nu ewa Re, 

   Ogo f'Olorun, Aleluya! 


Refrain

Omo Olorun ni eto lati bu s'ayo 

Pe ona yi nye wa si, 

Okan wa ns'aferi Re; 

Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo 

Ogo f'Olorun, Aleluya! 


  •  Nibe ao korin titun t'anu t'O da wa nde, 

   Ogo f'Olorun Aleluya! 

   Nibe awon ayanfe yo korin 'yin ti Krist; 

   Ogo f'Olorun, Aleluya! 


Refrain

Omo Olorun ni eto lati bu s'ayo 

Pe ona yi nye wa si, 

Okan wa ns'aferi Re; 

Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo 

Ogo f'Olorun, Aleluya! AMIN.


Click Here For English Version Of The Song

Post a Comment

أحدث أقدم