CCC Hymn 238 | Ìwé Orin 238



s: s: s: d: m: m: m: f: m: r
d: t: d: r: f: m: m: d
s: s: s: d: m: m: m: f: m: r
d: t: d: r: f: m: m: d
  • Ẹ̀ mímọ́, wa s'arin wa

baba orun lo paṣẹ na

isẹ dé rẹ tètè sọkalẹ

wa fi ọna rẹ hàn wa.


  • Emi mimo, e mi alaye e

wa ba s'ori awa ọmọ rẹ

ka wa le yín ọ ni kankan 

lati sisi yi lọ dopin


  • Emi mimo, emi at'orun wa

baba ọmọ Emi mimo

wa fi agbara wọ ijọ yi

k'iyin lejẹ t'ijọ alaye. Amin


Post a Comment

أحدث أقدم