CCC HYMNS 694 | Ìwé Orin mimo 694


  •  Ka sise fun iwenu mo emi wa

K'oluwa fi le wa pelu wa

Ka sise sise fun ijo Jehova

Ka si ranti orun mimo

Ka sise fun iwenu mo emi wa

Ka si ranti ile nla loke orun

Ka sise fun iwenu mo emi wa

Ka si ranti ile nla loke orun


  • K'oluwa jowo sokale sarin wa

Ka wa fi le ri iwenumo

Michael mimo ko ran wa lowo

Kuro ni nu idanwo aiye

Ka wa fi le segun emi esu

Ka sise pelu ife mimo

Ka wa fi le segun emi esu

Ka sise pelu ife mimo 


  • Asan ni f'eniyan lati f'okan fun

Isura aiye ti yio fo lo

O ye ka wa pejo ka sise

Ise ti Kristi ran wa

Eyi ni yio mu wa gb'ade ogo

Ti baba se leri re fun wa

Eyi ni yio mu wa gb'ade ogo

Ti baba se leri re fun wa.Amin

Post a Comment

أحدث أقدم