- Eyin araiye, e sin Jesu,
ebo kan yin s'oro
igbala mbe lowo re
e bo 'kan yin s'oro,
igbala mbe lowo re
- Awon ogun orun
nfun ipe
eiye iwo nfi yin
e bo 'kan yin s'oro
igbala mbe lowo re,
e bo 'kan yin s'oro
igbala mbe lowo re.
- Eyin araiye, e sin Jesu,
ebo kan yin s'oro
igbala mbe lowo re
e bo 'kan yin s'oro,
igbala mbe lowo re. Amin.
إرسال تعليق