- Ka sise fun iwenu mo emi wa
K'oluwa fi le wa pelu wa
Ka sise sise fun ijo Jehova
Ka si ranti orun mimo
Ka sise fun iwenu mo emi wa
Ka si ranti ile nla loke orun
Ka sise fun iwenu mo emi wa
Ka si ranti ile nla loke orun
- K'oluwa jowo sokale sarin wa
Ka wa fi le ri iwenumo
Michael mimo ko ran wa lowo
Kuro ni nu idanwo aiye
Ka wa fi le segun emi esu
Ka sise pelu ife mimo
Ka wa fi le segun emi esu
Ka sise pelu ife mimo
- Asan ni f'eniyan lati f'okan fun
Isura aiye ti yio fo lo
O ye ka wa pejo ka sise
Ise ti Kristi ran wa
Eyi ni yio mu wa gb'ade ogo
Ti baba se leri re fun wa
Eyi ni yio mu wa gb'ade ogo
Ti baba se leri re fun wa.Amin
Post a Comment