CCC Hymn 207 | Ìwé Orin mimo 207 Duru wura n'ke tantan

 


Duru  wura nke tantan

yi àgbàlá orun ka

adun lohun orin won

ti awọn angẹli nko

pẹlu iyin nlan 

wọn tẹ orí wọn ba

pẹlu ibọwọ la nla nla

wọn sì f'ogo f'ọlọrun

ogo ogo iyin fún bàbá

eleda orun ati aiye

aleluya, aleluya hossanah l'ohun orin won

aleluya, aleluya hossanah l'ohun orin won.  Amin



Post a Comment

Previous Post Next Post