- Ko su wa lati ma ko orin igbani
Ogo f'Olorun Aleluya!
A le fi igbagbo korin na s'oke kikan.
Ogo f'Olorun, Aleluya
Refrain
Omo Olorun ni eto lati bu s'ayo
Pe ona yi nye wa si,
Okan wa ns'aferi Re;
Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo
Ogo f'Olorun, Aleluya!
- Awa mbe n'nu ibu ife t'o ra wa pada,
Ogo f'Olorun Aleluya!
Awa y'o fi iye goke lo s'oke orun;
Ogo f'Olorun, Aleluya!
Refrain
Omo Olorun ni eto lati bu s'ayo
Pe ona yi nye wa si,
Okan wa ns'aferi Re;
Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo
Ogo f'Olorun, Aleluya!
- Awa nlo si afin kan ti a fi wura ko,
Ogo f'Olorun Aleluya!
Nibiti ao ri Oba Ogo n'nu ewa Re,
Ogo f'Olorun, Aleluya!
Refrain
Omo Olorun ni eto lati bu s'ayo
Pe ona yi nye wa si,
Okan wa ns'aferi Re;
Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo
Ogo f'Olorun, Aleluya!
- Nibe ao korin titun t'anu t'O da wa nde,
Ogo f'Olorun Aleluya!
Nibe awon ayanfe yo korin 'yin ti Krist;
Ogo f'Olorun, Aleluya!
Refrain
Omo Olorun ni eto lati bu s'ayo
Pe ona yi nye wa si,
Okan wa ns'aferi Re;
Nigb'o se a o de afin Oba wa Ologo
Ogo f'Olorun, Aleluya! AMIN.
Click Here For English Version Of The Song
Post a Comment