Duru wura nke tantan
yi àgbàlá orun ka
adun lohun orin won
ti awọn angẹli nko
pẹlu iyin nlan
wọn tẹ orí wọn ba
pẹlu ibọwọ la nla nla
wọn sì f'ogo f'ọlọrun
ogo ogo iyin fún bàbá
eleda orun ati aiye
aleluya, aleluya hossanah l'ohun orin won
aleluya, aleluya hossanah l'ohun orin won. Amin
Post a Comment